Duration 1:19:8

OWONRIN MEJI ODU AGBA

4 723 watched
0
394
Published 21 Jul 2021

Síbà lé mi Kí n síbà lé ợ Bí Yèrèpé ti síbà lÉèşún Ká jợ síbà léraa wa A dífá fún Sièjidé Sièjidé ti ó móợ sòwò Ợjà ń níná Ợmợ Ợba ni Sièjidé lóde Òyó Ợjà ní móợ ná Ó wáá tajà tajà Ợjàa rè ò tà Ó bá mú eéji kún ẹéta Ló bá tợ Òrúnmìlà lợ Ó ké si àwợn “Òwón Owó làá náwó mini” Àwợn “Òwón omi làá pèsun” Àwợn “N tó bá wón làá pè níyàn” Ó ní kí àwợn métèèta ó yẹ òun lóókan ibò wò Wón níwợ Sièjidé “Ó sòwò sòwò ợjàà rẹ ò tà lo dá Ifá yìí sí” Ệbợ ní kó rú Ợjàà ré ó sí móợ tà Sièjidé bá rúbợ Ó rúbợ tán ó bá bèrè síí lá N ní wá ń jó n ní ń yò Ní ń yin àwợn Babaláwo Àwợn Babaláwo ń yin Ifá Ó ní béè làwợn Babaláwo tòún wí Síbà lé mi Kí n síbà lé ợ Bí Yèrèpé ti síbà lÉèşún Ká jợ síbà léraa wa A dífá fún Sièjidé Sièjidé ti ó móợ sòwò Ợjà ń níná Èyí tíí sợmợ ợba lóde Òyó Ệbợ ń wón ní ó şe Ệ yáa wá rajà ợmợ ợba Ệ pò sinsin wáá ẹ wáá rajà ohùn yìí ó wón! Ệ yáa wá rajà ợmợ ợba.

Category

Show more

Comments - 25